Ezra 7:10 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nítorí Ẹsira fi gbogbo ọkàn rẹ̀ sí kíkọ́ òfin OLUWA, ati pípa á mọ́ ati kíkọ́ gbogbo àwọn ọmọ Israẹli.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori Esra ti mura tan li ọkàn rẹ̀ lati ma wá ofin Oluwa, ati lati ṣe e, ati lati ma kọ́ni li ofin ati idajọ ni Israeli.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ẹ́sírà ti fi ara rẹ̀ jìn fún kíkọ́ àti pípa òfin OLÚWA mọ́, ó sì ń kọ́ òfin àti ìlànà Mósè ní Ísírẹ́lì.