Ezra 8:14 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ninu àwọn ọmọ Bigifai, Utai ati Sakuri ni olórí, orúkọ aadọrin eniyan ni wọ́n kọ sílẹ̀ pẹlu wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ninu awọn ọmọ Bigfai pẹlu; Uttai, ati Sabbudi, ati pẹlu wọn, ãdọrin ọkunrin.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nínú àwọn ọmọ Bígífáyì, Hútayì àti Ṣákúrì, àti àádọ́rin 70 ọkúnrin pẹ̀lú wọn.