Ezra 8:16 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Mo bá ranṣẹ pe àwọn olórí wọn wọnyi: Elieseri, Arieli ati Ṣemaaya, Elinatani, Jaribu, Elinatani Natani, Sakaraya, ati Meṣulamu. Mo sì tún ranṣẹ pe Joiaribu ati Elinatani, tí wọ́n jẹ́ amòye.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbana ni mo ranṣẹ pè Elieseri, Arieli, Ṣemaiah, ati Elnatani ati Jaribi, ati Elnatani, ati Natani, ati Sekariah, ati Meṣullamu, awọn olori pẹlu Joiaribi, ati Elnatani, enia oloye.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ni mo pe Élíásérì, Áríélì, Ṣemanáyà, Elinátanì, Járíbù, Elinátánì, Nátanì, Ṣakaráyà, àti Mésúlámù, ti wọ̀n jẹ̀ olórí, àti Jóíáríbù àti Elinátanì ti wọ̀n jẹ́ onímọ̀ ìjìnlẹ̀,