Ezra 8:2 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ninu àwọn ọmọ Finehasi, Geriṣomu ni olórí. Ninu àwọn ọmọ Itamari, Daniẹli ni olórí. Ninu àwọn ọmọ Dafidi,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ninu awọn ọmọ Finehasi, Gerṣomu: ninu awọn ọmọ Itamari, Danieli: ninu awọn ọmọ Dafidi, Hattuṣi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nínú àwọn ọmọ Fínéhásì, Gásómù; nínú àwọn ọmọ Ítamárì, Dáníẹ́lì; nínú àwọn ọmọ Dáfídì, Hátúsì,