Ezra 8:24 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Lẹ́yìn náà mo ya àwọn àgbààgbà alufaa mejila sọ́tọ̀: Ṣerebaya, Haṣabaya ati mẹ́wàá ninu àwọn arakunrin wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbana ni mo yàn ẹni-mejila si ọ̀tọ ninu awọn olori awọn alufa, Ṣerebiah, Haṣabiah, ati mẹwa ninu awọn arakunrin wọn pẹlu wọn,
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ni mo yà àwọn àlùfáà tó jẹ́ aṣáájú méjìlá sọ́tọ̀, pẹ̀lú Ṣérébáyà, Hásábáyà àti mẹ́wàá lára àwọn arákùnrin wọn,