Ezra 8:3 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Hatuṣi, ọmọ Ṣekanaya, ni olórí. Ninu àwọn ọmọ Paroṣi, Sakaraya ni olórí; orúkọ aadọjọ (150) eniyan ni wọ́n kọ sílẹ̀ pẹlu rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ninu awọn ọmọ Ṣekaniah, ti awọn ọmọ Paroṣi, Ṣekariah: ati pẹlu rẹ̀ li a ka ãdọjọ ọkunrin nipa iwe itan-idile.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
nínú àwọn ọmọ Ṣekaníáyà; nínú àwọn ọmọ Párósì, Ṣekaríáyà, àti pé àádọ́jọ (150) ọkùnrin fi orùkọ sílẹ̀ pẹ̀lú rẹ;