Ezra 8:4 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ninu àwọn ọmọ Pahati Moabu, Eliehoenai, ọmọ Serahaya, ni olórí; orúkọ igba (200) eniyan ni wọ́n kọ sílẹ̀ pẹlu rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ninu awọn ọmọ Pahat-moabu; Elihoenai ọmọ Serahiah, ati pẹlu rẹ̀, igba ọkunrin.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
nínú àwọn ọmọ Pahati-Móábù, Elehóénáyì ọmọ Seraíyà àti àwọn igba (200) ọkùnrin pẹ̀lú rẹ̀;