Ezra 8:5 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ninu àwọn ọmọ Satu, Ṣekanaya, ọmọ Jahasieli, ni olórí; orúkọ ọọdunrun (300) eniyan ni wọ́n kọ sílẹ̀ pẹlu rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ninu awọn ọmọ Ṣekaniah; ọmọ Jahasieli, ati pẹlu rẹ̀, ọdunrun ọkunrin.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
nínú àwọn ọmọ Ṣátù, Ṣekaníáyà ọmọ Jahasíélì àti àwọn ọ̀ọ́dúnrún (300) ọkùnrin pẹ̀lú rẹ̀;