Ezra 8:6 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ninu àwọn ọmọ Adini, Ebedi, ọmọ Jonatani, ni olórí; orúkọ aadọta eniyan ni wọ́n kọ sílẹ̀ pẹlu rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ninu awọn ọmọ Adini pẹlu, Ebedi ọmọ Jonatani, ati pẹlu rẹ̀, ãdọta ọkunrin.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
nínú àwọn ọmọ Ádínì, Ébédì ọmọ Jónátanì, àti àádọ́ta (50) ọkùnrin pẹ̀lú rẹ̀;