Ezra 8:7 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ninu àwọn ọmọ Elamu, Jeṣaya, ọmọ Atalaya, ni olórí; orúkọ aadọrin eniyan ni wọ́n kọ sílẹ̀ pẹlu rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati ninu awọn ọmọ Elamu; Jeṣaiah ọmọ Ataliah, ati pẹlu rẹ̀, ãdọrin ọkunrin.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
nínú àwọn ọmọ Élámù, Jésáíyà ọmọ Ataláyà àwọn àádọ́rin (70) ọkùnrin pẹ̀lú rẹ̀;