Ezra 9:3 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nígbà tí mo gbọ́ bẹ́ẹ̀, mo fa aṣọ ati agbádá mi ya, láti fi ìbànújẹ́ mi hàn, mo sì fa irun orí ati irùngbọ̀n mi tu; mo sì jókòó pẹlu ìbànújẹ́.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbati mo si gbọ́ nkan wọnyi, mo fa aṣọ mi ati agbáda mi ya, mo si fà irun ori mi ati ti àgbọn mi tu kuro, mo si joko ni ijaya.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà tí mo gbọ́ èyí, mo fa àwọ̀tẹ́lẹ̀ àti agbádá mi ya, mo ja irun orí àti irungbọ̀n mi, mo sì jókòó ní ìbànújẹ́.