Galatians 1:2 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Èmi ati gbogbo arakunrin tí ó wà lọ́dọ̀ mi ni à ń kọ ìwé yìí sí àwọn ìjọ Galatia.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati gbogbo awọn arakunrin ti o wà pẹlu mi, si awọn ijọ Galatia:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àti gbogbo àwọn arákùnrin tí ó wà pẹ̀lú mi, Sí àwọn ìjọ ní Gálátíà: