Galatians 2:10 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nǹkankan ni wọ́n sọ fún wa, pé kí á ranti àwọn talaka láàrin àwọn tí ó kọlà. Òun gan-an ni mo sì ti dàníyàn láti máa ṣe.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Kìki nwọn fẹ ki a mã ranti awọn talakà, ohun kanna gan ti mo nfi titaratitara ṣe pẹlu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ohun gbogbo tí wón bèèrè fún ni wí pé kí a máa rántí àwọn tálákà, ohun kan náà gan-an tí mo ń làkàkà láti ṣe.