Galatians 2:3 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Kì í ṣe ọ̀ranyàn ni pé kí á kọ Titu tí ó wà pẹlu mi nílà nítorí pé ọmọ ẹ̀yà Giriki ni.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn a kò fi agbara mu Titu ti o wà pẹlu mi, ẹniti iṣe ara Hellene, lati kọla:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n a kò fi agbára mú Títù tí ó wà pẹ̀lú mi, ẹni tí í ṣe ara Gíríkì láti kọlà.