Galatians 2:5 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ṣugbọn a kò fi ìgbà kankan gbà wọ́n láyè rárá, kí ó má dàbí ẹni pé ọ̀rọ̀ tiwọn ni ó borí, kí òtítọ́ ìyìn rere lè wà pẹlu yín.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ẹniti awa kò si fi àye fun lati dari wa fun wakati kan; ki otitọ ìhinrere ki o le mã wà titi pẹlu nyin.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Fún wọn, a kò tilẹ̀ fí ààyè sílẹ̀, nígbà kan rárá; kí òtítọ́ ìyìn rere lè máa wà títí pẹ̀lú yin.