Galatians 3:27 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nítorí gbogbo ẹni tí ó ti ṣe ìrìbọmi nípa igbagbọ ninu Kristi ti gbé Kristi wọ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitoripe iye ẹnyin ti a ti baptisi sinu Kristi, ti gbe Kristi wọ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí pé iye ẹ̀yin tí a ti baptisti sínú Kírísítì ti gbé Kírísítì wọ̀.