Genesis 10:16 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Kenaani yìí kan náà ni baba ńlá àwọn ará Jebusi, àwọn ará Amori, àwọn ará Girigaṣi,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati awọn ara Jebusi, ati awọn ara Amori, ati awọn ara Girgaṣi,
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ará Jébúsì, Ámórì, Gágásì.