Genesis 10:18 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
àwọn ará Arifadi, àwọn ará Semari, ati àwọn ará Hamati. Lẹ́yìn náà ni ìran àwọn ará Kenaani tàn káàkiri.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati awọn ara Arfadi, ati awọn ara Semari, ati awọn ara Hamati; lẹhin eyini ni idile awọn ara Kenaani tàn kalẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Áfádì, Ṣémárì àti Hámátì. Nígbà tí ó ṣe, àwọn ẹ̀yà Kénánì tàn kálẹ̀.