Genesis 10:29 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ṣeba, Ofiri, Hafila, ati Jobabu, àwọn ni ọmọ Jokitani.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati Ofiri, ati Hafila, ati Jobabu: gbogbo awọn wọnyi li ọmọ Joktani.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ófírì, Áfílà àti Jóbábù. Gbogbo àwọn wọ̀nyí ni ọmọ Jókítanì.