Genesis 12:3 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
N óo súre fún àwọn tí wọ́n bá súre fún ọ, bí ẹnikẹ́ni bá sì fi ọ́ bú, n óo fi òun náà bú. Nípasẹ̀ rẹ ni n óo bukun gbogbo ìdílé ayé.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Emi o bukun fun awọn ti nsúre fun ọ, ẹniti o nfi ọ ré li emi o si fi ré; ninu rẹ li a o ti bukun fun gbogbo idile aiye.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn tí ó súre fún ọ ni Èmi yóò súre fún, ẹnikẹ́ni tí ó bá sì fi ọ́ ré ni Èmi yóò fi ré; Nípaṣẹ̀ rẹ ni a ó sì bùkún gbogbo ènìyàn ayé”