Genesis 17:25 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Iṣimaeli ọmọ rẹ̀ jẹ́ ọmọ ọdún mẹtala nígbà tí òun náà kọlà abẹ́.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati Iṣmaeli ọmọ rẹ̀ ọkunrin jẹ ẹni ọdún mẹtala nigbati a kọ ọ ni ilà ara rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ísímáélì ọmọ rẹ̀ jẹ́ ẹni ọdún mẹ́talá, (13).