Genesis 18:17 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
OLUWA sọ pé, “Mo ha gbọdọ̀ fi ohun tí mo fẹ́ ṣe yìí pamọ́ fún Abrahamu,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
OLUWA si wipe, Emi o ha pa ohun ti emi o ṣe mọ́ fun Abrahamu:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ni OLÚWA wí pé, “Ǹjẹ́ èmi yóò ha pa ohun tí mo fẹ́ ṣe mọ́ fún Ábúráhámù bí?