Genesis 18:9 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nígbà tí wọ́n jẹun tán, wọ́n bi í pé, “Níbo ni Sara aya rẹ wà?” Ó dá wọn lóhùn pé, “Ó wà ninu àgọ́.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn si bi i pe, nibo ni Sara aya rẹ wà? o si wipe, wò o ninu agọ́.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọn bèèrè pé, “Ṣárà aya rẹ ńkọ́?” Ó dáhùn pé, “Ó wà nínú àgọ́.”