Genesis 19:10 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn àjèjì náà bá fa Lọti wọlé, wọ́n ti ìlẹ̀kùn,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn awọn ọkunrin na nà ọwọ́ wọn, nwọn si fà Loti mọ́ ọdọ sinu ile, nwọn si tì ilẹkun.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n àwọn ọkùnrin náà nawọ́ fa Lọ́tì wọlé, wọ́n sì ti ilẹ̀kùn.