Genesis 19:36 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Bẹ́ẹ̀ ni àwọn ọmọ Lọti mejeeji ṣe lóyún fún baba wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bẹ̃li awọn ọmọbinrin Loti mejeji loyun fun baba wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ọmọbìnrin Lọ́tì méjèèjì sì lóyún fún baba wọn.