Genesis 2:6 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ṣugbọn omi kan a máa ru jáde láti inú ilẹ̀ láti mú kí gbogbo ilẹ̀ rin.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn ikũku a ti ilẹ wá, a si ma rin oju ilẹ gbogbo.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n ìsun omi ń jáde láti ilẹ̀, ó sì ń bu omi rin gbogbo ilẹ̀.