Genesis 21:11 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ọ̀rọ̀ yìí kò dùn mọ́ Abrahamu ninu nítorí Iṣimaeli, ọmọ rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ọrọ yi si buru gidigidi li oju Abrahamu nitori ọmọ rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ọ̀rọ̀ náà sì ba Ábúráhámù lọ́kàn jẹ́ gidigidi nítorí ọmọ rẹ̀ náà sáà ni Isìmàẹ́lì i ṣe.