Genesis 21:15 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nígbà tí omi tán ninu ìgò aláwọ náà, Hagari fi ọmọ náà sílẹ̀ lábẹ́ igbó ṣúúrú kan tí ó wà níbẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Omi na si tán ninu ìgo, o si sọ̀ ọmọ na si abẹ ìgboro kan.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà tí omi inú ìgò náà tan, ó gbé ọmọ náà sí abẹ́ igbó.