Genesis 23:16 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Abrahamu gbà bí Efuroni ti wí, ó bá wọn irinwo (400) ìwọ̀n ṣekeli fadaka tí Efuroni dárúkọ fún un lójú gbogbo wọn, ó lo ìwọ̀n tí àwọn oníṣòwò ìgbà náà ń lò.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Abrahamu si gbọ́ ti Efroni; Abrahamu si wọ̀n iye fadaka na fun Efroni, ti o sọ li eti awọn ọmọ Heti, irinwo òṣuwọn ṣekeli fadaka, ti o kọja lọdọ awọn oniṣòwo.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ábúráhámù sì gba ohun tí Éfúróni wí, ó sì wọn iye owó fàdákà náà lójú gbogbo ènìyàn: irínwó owó idẹ fàdákà gẹ́gẹ́ bí ìwọ̀n oníṣòwò ayé ìgbà náà.