Genesis 23:7 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Abrahamu bá dìde, ó tẹríba níwájú wọn,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Abrahamu si dide duro, o si tẹriba fun awọn enia ilẹ na, fun awọn ọmọ Heti.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ni Ábúráhámù dìde, ó sì tẹríba níwájú àwọn ará ilẹ̀ náà-àwọn ará Hítì.