Genesis 24:28 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ọmọbinrin náà bá sáré lọ sọ gbogbo ohun tí ó ṣẹlẹ̀ fún àwọn ará ilé ìyá rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Omidan na si sure, o si rò nkan wọnyi fun awọn ara ile iya rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ọmọbìnrin náà sì sáré, ó sì lọ sọ ohun gbogbo wọ̀nyí fún àwọn ará ilé ìyá rẹ̀.