Genesis 24:34 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ọkunrin náà bẹ̀rẹ̀ ọ̀rọ̀ rẹ̀, ó ní, “Iranṣẹ Abrahamu ni mí,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O si wipe, Ọmọ-ọdọ Abrahamu li emi iṣe.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí náà ó wí pé, “Ìránṣẹ́ Ábúráhámù ni èmi.