Genesis 24:39 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Mo sì bi oluwa mi nígbà náà pé, ‘bí obinrin náà bá kọ̀ láti bá mi wá ńkọ́?’
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Emi si wi fun oluwa mi pe, Bọya obinrin na ki yio tẹle mi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Mo sì bí olúwa mi léèrè pé, ‘Ǹjẹ́ bí ọmọbìnrin náà kò bá fẹ́ bá mi wá ńkọ́?’