Genesis 24:50 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Labani ati Betueli dáhùn pé, “Ati ọ̀dọ̀ OLUWA ni nǹkan yìí ti wá, àwa kò sì ní sọ pé bẹ́ẹ̀ ni tabi bẹ́ẹ̀ kọ́.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbana ni Labani ati Betueli dahùn nwọn si wipe, Lọdọ OLUWA li ohun na ti jade wá: awa kò le sọ rere tabi buburu fun ọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Lábánì àti Bétúélì sì dáhùn pé, “Lọ́dọ̀ OLÚWA ni èyi ti wá, nítorí náà àwa kò le sọ rere tàbí búburú fún ọ.