Genesis 24:52 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nígbà tí iranṣẹ Abrahamu gbọ́ ohun tí wọ́n sọ, ó wólẹ̀ ó sì dojúbolẹ̀ níwájú OLUWA.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O si ṣe, nigbati iranṣẹ Abrahamu gbọ́ ọ̀rọ wọn, o wolẹ fun OLUWA.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà tí ọmọ-ọ̀dọ̀ Ábúráhámù gbọ́ ohun tí wọ́n wí, ó wólẹ̀ níwájú OLÚWA.