Genesis 24:57 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Wọ́n dáhùn pé, “Ẹ jẹ́ kí á kúkú pe omidan náà kí á bèèrè lọ́wọ́ rẹ̀.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn si wipe, Awa o pè omidan na, a o si bère li ẹnu rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ni wọ́n sọ pé, “Jẹ́ kí a pe ọmọ náà gan-an kí a sì bi í”