Genesis 24:66 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nígbà tí wọ́n pàdé Isaaki, iranṣẹ náà ròyìn gbogbo ohun tí ó ṣẹlẹ̀ fún un.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Iranṣẹ na si rò ohun gbogbo ti on ṣe fun Isaaki.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ni ìránṣẹ́ náà ròyìn fún Ísáákì ohun gbogbo tí ó ti ṣe.
Recommended Reading