Genesis 26:35 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn obinrin mejeeji yìí han Isaaki ati Rebeka léèmọ̀ tóbẹ́ẹ̀ tí ayé sú wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ohun ti o ṣe ibinujẹ fun Isaaki ati fun Rebeka.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Fífẹ́ tí a fẹ́ àwọn obìnrin wọ̀nyí jẹ́ ìbànújẹ́ fún Ísáákì àti Rèbékà.