Genesis 27:39 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nígbà náà ni Isaaki, baba rẹ̀, dá a lóhùn, ó ní, “Níbi tí ilẹ̀ kò ti lọ́ràá ni o óo máa gbé, níbi tí kò sí ìrì ọ̀run.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Isaaki baba rẹ̀ si dahùn o si wi fun u pe, Wõ, ibujoko rẹ yio jẹ ọrá ilẹ, ati ibi ìri ọrun lati oke wá;
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ísáákì bàbá rẹ̀ sì dá a lóhùn pé, “Ibùjòkòó rẹ yóò jìnnà sí ọ̀rá ilẹ̀, àti sí ìrì ọ̀run láti òkè wá.