Genesis 28:22 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Òkúta tí mo sì gbé nàró bí ọ̀wọ̀n yìí yóo di ilé Ọlọrun, n óo sì fún ìwọ Ọlọrun ní ìdámẹ́wàá ohun gbogbo tí o bá fún mi.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Okuta yi, ti mo fi lelẹ ṣe ọwọ̀n ni yio si ṣe ile Ọlọrun: ati ninu ohun gbogbo ti iwọ o fi fun mi, emi o si fi idamẹwa rẹ̀ fun ọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Òkúta yìí tí mo gbé kalẹ̀ bí ọ̀wọ̀n yóò jẹ́ ilé Ọlọ́run, gbogbo ohun tí O bá sì fún mi, èmi yóò fún Ọ ní ìdámẹ́wàá rẹ̀.”