Genesis 29:1 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Jakọbu tún ń bá ìrìn àjò rẹ̀ lọ, nígbà tí ó ṣe, ó dé ilẹ̀ àwọn ará ìlà oòrùn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
JAKOBU si mu ọ̀na àjo rẹ̀ pọ̀n, o si wá si ilẹ awọn ara ìla-õrùn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Jákọ́bù sì tẹ̀ṣíwájú nínú ìrìn-àjò rẹ̀, ó sì dé ilẹ̀ àwọn ará ìlà oòrùn.