Genesis 32:23 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ó kó àwọn ati ohun gbogbo tí ó ní kọjá sí ìhà keji odò.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O si mú wọn, o si rán wọn si oke odò na, o si rán ohun ti o ní kọja si oke odò.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Lẹ́yìn ìgbà tí ó ti rán wọn kọjá odò tán sí òkè-odò, ó sì rán àwọn ohun-ìní rẹ̀ kọjá pẹ̀lú.