Genesis 35:26 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn tí Silipa, iranṣẹbinrin Lea bí ni: Gadi ati Aṣeri. Àwọn wọnyi ni àwọn ọmọ tí wọ́n bí fún Jakọbu ní Padani-aramu.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati awọn ọmọ Silpa, iranṣẹbinrin Lea; Gadi ati Aṣeri. Awọn wọnyi li ọmọ Jakobu, ti a bí fun u ni Padanaramu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ọmọ Ṣílípà ìránṣẹ́-bìnrin Líà: Gádì àti Áṣérì. Àwọn wọ̀nyí ni ọmọ tí Jákọ́bù bí ní Padani-Árámù.