Genesis 36:15 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn tí wọ́n jẹ́ ìjòyè ninu àwọn ọmọ Esau nìwọ̀nyí, Lára àwọn ọmọ Elifasi, àkọ́bí Esau, tí Ada bí fún un: Temani, Omari, Sefo, Kenasi.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn wọnyi ni olori ninu awọn ọmọ Esau: awọn ọmọ Elifasi, akọ́bi Esau; Temani olori, Omari olori, Sefo olori, Kenasi olori,
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọn wọ̀nyí ni olórí nínú àwọn ọmọ Ísọ̀: Àwọn ọmọ Élífásì, àkọ́bí Ísọ̀: Témánì, Ómárì, Ṣéfò, Kénásíà,