Genesis 36:25 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn ọmọ Ana ni, Diṣoni ati Oholibama.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Wọnyi si li awọn ọmọ Ana; Disoni ati Aholibama, ọmọbinrin Ana.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọ̀nyí ni àwọn ọmọ Ánà: Dísónì àti Óhólíbámà (Àwọn ọmọbìnrin ni wọn).