Genesis 36:8 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Bẹ́ẹ̀ ni Esau ṣe di ẹni tí ń gbé orí òkè Seiri. Esau kan náà ni ń jẹ́ Edomu.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bẹ̃ni Esau tẹ̀dó li oke Seiri: Esau ni Edomu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Báyìí ni Ísọ̀ tí a tún mọ̀ sí Édómù tẹ̀dó sí àwọn orílẹ̀ èdè oloke tí Ṣéírì.