Genesis 37:12 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ní ọjọ́ kan àwọn arakunrin rẹ̀ ń da agbo aguntan baba wọn lẹ́bàá Ṣekemu,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn arakunrin rẹ̀ si lọ lati bọ́ agbo-ẹran baba wọn ni Ṣekemu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn arákùnrin rẹ̀ sì da ẹran baba wọn lọ sí Ṣékémù.