Genesis 37:24 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
wọ́n gbé e jù sinu kànga kan tí kò ní omi ninu.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn si mú u, nwọn si gbe e sọ sinu ihò kan: ihò na si gbẹ, kò li omi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
wọ́n mú un, wọ́n sì jù ú sínú kòtò. Kòtò náà sì ṣófo, kò sí omi nínú un rẹ̀.