Genesis 38:10 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ohun tí Onani ń ṣe yìí kò dùn mọ́ Ọlọrun ninu, Ọlọrun bá pa òun náà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ohun ti o si ṣe buru loju OLUWA, nitori na li OLUWA pa a pẹlu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ohun tí ó ń ṣe yìí burú lójú OLÚWA, ó sì pa òun náà pẹ̀lú.