Genesis 40:2 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Inú bí Farao sí àwọn iranṣẹ rẹ̀ mejeeji yìí,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Farao si binu si meji ninu awọn ijoye rẹ̀, si olori awọn agbọti, ati si olori awọn alasè.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Fáráò sì bínú sí méjì nínú àwọn ìjòyè rẹ̀, olórí agbọ́tí àti olórí alásè,